Mọ iye ọdún tó ṣeéṣe kí o lò láyé

Njẹ́ o mọ̀ pé iye ọdún tó ṣeéṣe kí gbogbo ènìyàn yóò lò láyé ti fi ọdún méje pọ̀ si láti 1990?

Irinṣẹ́ òǹkà yìí yóò ràn ọ́ lọ́wọ́ láti ṣe ìṣìrò tìrẹ̀ ní ìbámu pẹ̀lú orílẹ̀èdè tí o ti wá.

Ọdun mejilelaadọrin nireti wa pe o jẹ ọdun to kere ju ti ẹda yoo lo laye - aadọrin ọdun fun ọkunrin, marundinlọgọrin fun obinrin. Ṣugbọn, eyi n yipada pẹlu ọjọ ori. Fun apẹẹrẹ,ireti wa pe ẹni ti o ti pe ọdun mọkandinlaadọrin yoo lo ọdun mẹtadinlogun si.

Móríwú

  • Àwòrán ológbò aláwọ̀ àrán tó jókòó lórí àga
  • Ọkọ Akẹru kan ko awọn ero sinu ọkọ, o n lọ loju popo kan ti ọna rẹ ko dara
  • Àgbà òṣèré Lere Paimo wọ ìgò ojú, ó jókòó, ó ń wo ọ̀ọ́kán
  • Pasitọ to lọ gbadura nidi Osun ati Oba Ido-Osun
  • Ọkunrin kan n fi ike bu omi lati oju ferese
  • Tunde Usman, Okele
  • Omidan Titilayo Ibrahim to wọ asọ awọn to n sinru ilu tii se asọ toke tilẹ funfun, bata tẹnisi funfun ati fila NYSC
  • Ìdí tí dókítà ń fi ọwọ́ tẹ̀
  • Awọn ọdọ mẹta n rẹrin-in bi wọn ṣe n takurọsọ
  • Aworan DJ Cuppy

Ìròyìn tí àwọn ènìyàn fẹ́ràn jùlọ